Olùdarí Ìròyìn Orí Ayélujára Tí Ilè Akéde Nàìjíríà Ṣé Ẹ̀yẹ Ìkẹhìn Fún Màmá Rẹ̀
Hajia Maryam Olabisi Yusuf tó jẹ Ìyá Olùdarí Ìròyìn Ayélujára tí Ilè Akéde Nàìjíríà (VON), Hajia Sani, tí jáde láyé ní Ìlu Abùjá, Olúìlú Orílẹ̀-èdè yìí, tí wọ́n sí sìn ní ìlànà Islam ní Ilú Ilorin, Olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Kwara.
Olóògbé…