UNGA 78: Nàìjíríà darapọ̀ mọ́ akitiyan àgbáyé láti rẹ́yìn ikọ́ àwúgbẹ
Nàìjíríà, pẹlu awọn orilẹ-ede Ajọ Iṣọkan, Aṣoju ẹgbẹ ara ilu, ati awọn awọn ti o tun nii lọ́kàn, ti fọwọsi ikede lati ṣe agbekalẹ eto láti rẹ́yìn ikọ́ àwúgbẹ (TB) ni kiakia ni ọdun 2030.
Iwe naa ṣalaye erongba tuntun ni ọdun…