Manchester City Gbá Omijé Lójú Inter Milan Látí Gbá Ìfé UEFA Champions League
Ẹgbẹ́ àgbábọ́ọ̀lù Manchester City parí sáà ìgbábọ́ọ̀lù 2022/2023 ní ọnà àrà bó ṣé f'ojú Inter Milan gbọ́lẹ̀ nínú ìdíje tí UEFA Champions League pẹ̀lú àmì ayò 1-0 fún ìgbà àkọ́kọ́ nínú ìtàn wọ́n, ní pápá ìṣere Ataturk Olympic Stadium ní…