Nàìjíríà Rán Àwọn Aṣojú Giga Ránṣẹ Fún Ìsìnkú Pope Francis
Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu tí rán ìkọ àwọn àgbà Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kán lọ́ sílùú Vatican látí lọ́ sí bí ìsìnkú Pope Francis, ní ọjọ́ Àbámẹ́ta, ọjọ́ kẹ́rin dín lọgọ̀n, ọdún yìí.
Ààrẹ Ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà, Godswill Akpabio ní olórí àwọn…