Aarẹ Buhari ti se gudugudu méje, yàyà mẹ́fa fún Nàíjíríà- Gomina Jigawa
Gomina ìpínlẹ̀ Jigawa , Muhammadu Badaru ti gbóríyìn fún ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà , Muhammadu Buhari fún gudu gudu méje , yàyà mẹ́fà tí ó ń se fún gbogbo ọmọ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà,pàápàá jùlọ lórí…