Nàìjíríà, Saudi Arabia Bẹ̀rẹ̀ àjọṣepọ̀ láti kojú Boko Haram, ISWAP
Ààrẹ Nàìjíríà, Bọla Ahmed Tinubu ti sọ pé Nàìjíríà ti ṣetán láti jọ ṣiṣẹ́pọ̀ pẹ̀lú Saudi Arabia láti kojú ẹgbẹ́ oníjàgídíjàgan bíi Boko Haram, ISWAP, àti àwọn ẹgbẹ́ alákatakítí mìíràn.
Nigba ti o n sọrọ…