Russia Kìlọ̀ Fún America Lórí Àwọn Òun-ìní Rẹ̀
Russia tí kìlọ̀ pé yóó fèsì sí ìgbésẹ̀ ìwọ̀-oòrùn látí gbá àwọn òun-ìní rẹ̀ tàbí kojú awọn òun ìjà.
Russia ṣetán láti pín àwọn ìbátan rẹ̀ pẹ̀lú America tó bá jẹ́ kí wọ́n gbá àwọn òun-ìní Russia tó wà lábẹ́ rẹ̀, Ìgbákejì Mínísítà ilẹ̀…