Ìgbésẹ Ààrẹ Tinubu Lórí Ètò Ọrọ̀-ajé Ní A Ṣé Àkíyèsí Rẹ̀ Ní Àgbáyé
Kọmisọna àgbà tí Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì sí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Richard Montgomery sọ pé àwọn ìpinnu ètò-ọrọ̀ àjé tí ìṣàkóso Ààrẹ Bola Tinubu ní a ṣé àkíyèsí kàákiri àgbáyé àti pé yóò fá àwọn oníṣòwò wàá sí orílẹ̀-èdè náà.
Montgomery sọ èyí ní…