Ààrẹ Tinubu Ń Ṣé Ìpàdé Pẹ̀lú Àwon Olórí Ààbò
Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu tí wà ní ìpàdé báyìí pẹ̀lú àwọn alákóso ètò Ààbò orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí ọgá àgbà ológun, General Lucky Irabor, lé iwájú, ní Ilé-iṣẹ́ Ààrẹ, Abuja.
Ọgágún náà ló ṣíwájú fún àwọn ọgá àgbà Ilé-iṣẹ́ Ààbò mìíràn bíi…