Ààrẹ Tinubu Gbéra Ní Ìlú Abuja Fún Ìpàdé G20
Ààrẹ Nàìjíríà, Bola Tinubu tí gbéra kúrò ní Abuja ní àárọ̀ Ọjọ́ Ajé látí lọ sí Àpéjọ Awọn ìgbìmọ̀ G-20 ní New Delhi, India, lórí ifiwe pé pàtàkì tí Alákóso India, Narendra Modi.
Nínú àtẹ̀jáde kàn tí olùdámọ̀ràn pàtàkì fún Ààrẹ lórí ètò…