Ààrẹ Tinubu Dá Owó-Orí Dúró Lórí Àwọn Ilé-iṣẹ́ Ẹrọ Ìbánisọ́rọ́
Ààrẹ Bola Tinubu tí fọwọ́ sí dídádúró tí ìpín márùn-ún nínú ọgọ́rùn-ún owó-orí "Excise Tax" lórí ilé-iṣẹ́ ìbánisọ̀rọ̀ lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Ó tún ti fọwọ́sí ìdádúró owó-orí "Excise Duty" tí àwọn ilé-iṣẹ́ ilẹ̀ wà.
Olùdámọ̀ràn pàtàkì…