Igbákejì ààrẹ, Òsínbàjò ń darí ìgbìmọ̀ ìjọba àpapọ̀
Igbákejì ààrẹ orílẹ̀-èdè,ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmí Ọ̀sínbàjò ń darí ìgbìmọ̀ ijọba apapọ aláṣẹ lórí ayélujára,èyí tí ó bẹ̀rẹ̀ ní agogo mẹ́wàá òwúrọ̀ ní ọjọ́ọ́rú.
O jẹ ipade igbimọ akọkọ lati igba ti aarẹ Muhammadu…