Orílè èdè south africa yoo mu idagbasoke ba ilé-isẹ́
Orílè èdè south africa ti fowọsi àtìlẹ́yìn fún ilé-isé irin, ẹ̀ka ti ìsòwò àti ti ìdíje.
Ijọba ati awọn ti ọrọ kan ti fọsi owo to le ni ẹẹdẹgbẹfa biliọnu fun eto idagbasoke irin.
ọna mẹfa ni ijọba pin ipinnu ti wọn se…