Omíyalé gbẹ̀mí ènìyàn mẹ́tàdín-lógún ní Àringbùngbùn DR Congo
Ilẹ̀ jíjìn ti gbẹ̀mí àwọn ènìyàn mẹ́tàdín-lógún ní orílẹ̀-èdè Congo.
Ajalu naa ṣẹlẹ ni alẹ ọjọ Aiku lẹgbẹ eti omi Congo, ní Àringbùngbùn ilu Lisala, olu ilu agbegbe Mongala.
Awọn obinrin meje, ọkunrin meje, ati awọn…