Ààrẹ Tinubu yan Jamila Bio, Ọlawande ní Mínísítà Fún àwọn ọ̀dọ́
Ààrẹ Nàìjíríà, Bọla Ahmed Tinubu ti buwọ́lu yíyan Dókítà Jamila Bio Ibrahim fún Mínísítà fún àwọn ọ̀dọ́, títí di ìfìdímúlẹ̀ rẹ̀ láti ilé ìgbìmọ̀ Aṣòfin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Oludamọran pataki fun aarẹ…