Ojúmọ́ tuntun àrà tuntun:Wọ́n tún jí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ gbé ní ìpínlẹ̀ Niger
Àwọn ọlọ́pàá ti fìdíẹ̀ múlẹ̀ pé lótìtọ́ọ́ ni àwọn kan ti fipá kó àwọn ọmọ ilé-kéu ́ọkùnrin kan kúrò ní ilé-ìkawé wọn ní agbègbè Tegina ní ìjọba ìbílẹ̀ Rafi, ipinlẹ Niger ní ọjọ́ àìkú.
Gẹgẹ bii agbẹnusọ…