NAWOJ Ìpínlẹ̀ Ogun Kẹ́dùn Ikú Bukola Agbakaizu
Ẹgbẹ́ Akọ̀ròyìn Obínrin lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà (NAWOJ) ẹká tí Ìpínlẹ̀ Ogun tí fí ìbànújẹ ọkàn wọ́n hàn lórí ikú ọkán lára àwọn ọmọ ẹgbẹ́ wọ́n, Iyaafin Bukola Agbakaizu.
Ìyáfín Agbakaizu, ẹni ọdún méjìlèlàádọta, tún jẹ́ ọkan nínú àwọn…