Olùdarí àgbà fún àjọ àgùnbánirọ̀, NYSC kìlọ̀ fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ láti yàgò fún…
Olùdarí Àgbà fún ẹgbẹ́ àgùnbánirọ̀, (NYSC) ní orílè-èdè Nàìjíríà,ajagun Shuaibu Ibrahim, ti kìlọ̀ fún àwọn ọmọ ẹgbẹ láti máá ṣe lọ́wọ́sí ọ̀rọ̀ òṣèlú gẹ́gẹ́ bí ìdìbò gbogboogbo ọdún 2023 ti ń súnmọ́.…