NPFL: Ìfẹsẹ́wọ́nsẹ́ Bendel Insurance Àtí Enyimba Gbóná Gidigidi, Nígbàtí Rangers Lú Doma United
Enyimba FC tó gbá ife ẹyẹ́ 'Nigeria Premier Football League NPFL' tí ọdún tó kọjá gbá àmì ayò 0-0 pẹ̀lú Bendel Insurance nínú ìdíje náà, nígbà tí Rangers International lú olúgbàlejò rẹ̀ Doma United ní àmì ayò 1-0 lọ́jọ́ Àbámẹ́ta ní pápá…