NITDA – Ẹ máá jẹ́ kí enìkan tàn yín jẹ o
Léyìn ìfilọ́lẹ̀ owó ẹ̀rọ ayélujára tí ilé ìfowópamọ́ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ṣe láìpẹ́ yìí,àjọ tó ń ṣàkóso ètò ìmọ̀ ẹ̀rọ ní Nàìjíríà,NITDA ti kìlọ̀ fún àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti ṣọ́ra…