Ààrẹ Tinubu Yóò Kéde Ọjọ́ ikaniyan Túntún Láìpẹ́ Yìí – NPC
Ààrẹ Bola Tinubu ti rọ àjọ National Population Commission NPC láti tẹ̀ síwájú pẹ̀lú ìmúrasílẹ̀ fún kíkà ìyè àwọn ènìyàn orílẹ̀-èdè tí wọ́n sun síwájú.
Alága tí NPC, Nasir Kwarra sọ fún àwọn oníròyìn Ilé-iṣẹ́ Ààrẹ lẹyìn tó ṣé aṣojú…