Super Falcons Peregede Sí Ìpélé Òní Ìkọ Mẹ́rìndínlógún Níbí Ìfé Àgbáyé Àwọn Obìnrin
Super Falcons ti Nàìjíríà tí yégé sí ìpélé òní ìkọ mẹ́rìndìlogùn nínú ìdíje Àgbáyé tí àwọn Obìnrin 'FIFA Women’s World Cup' tí ọdún 2023 fún ìgbà kẹta lẹyìn tí wọ́n tá 0-0 pẹ̀lú ìkọ Republic of Ireland ní ọjọ́ Ajé.
Ìfẹ́sẹ́wọ́nsẹ́ tó…