Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Di Alága ILO Lẹyìn Ìdìbò
Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní wọ́n tí yán gẹ́gẹ́ bí Alága Ìgbìmọ̀ fún ẹgbẹ òṣìṣẹ́ lágbayé, (International Labour Organisation ILO).
Ìdìbò náà jẹ́ ọkàn nínú àwọn iṣẹ́ tó parí ọdún àpéjọ àwọn òṣìṣẹ́ Káríayé tí ILO tí ọdún yìí, èyí tó wáyé ní…