Àwọn Ẹgbẹ́ Kàn Kóró Ojú Sí Ìlànà Títà Àwọn Òun Ìní Ìjọba
Ẹgbẹ́ Alátagbà Nàìjíríà (Nigeria Association of Auctioneers NAA), tí bú ẹnu àtẹ́ lú bí ìjọba ṣé ń pàdánù àwọn owó ribiribi nípasẹ̀ bí wọ́n ṣé ń tá àwọn òun ìní tí ilé ẹjọ́ gbà nipasẹ̀ ìwà ajẹbanu lọ́nà àìtọ́ látàrí àìsí òdodo tí àwọn ilé…