NFF-A ó san owóo olùkọ́ni Peseiro
Àjọ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ́lù lápapọ̀, NFF, ti gbà pé òun jẹ olùkọ́ni Super Eagle Jose Peseiro ní owó osù.
Àwọn akọ̀ròyìn ti sọ ní ọ̀sẹ̀ yìí pé wọ́n jẹ Pọtugí ní gbèsè owó oṣù mẹ́fà.
Peseiro,tí ó jẹ́ ọmọ ọdún…