Ẹgbẹ́ Àwùjọ Aráàlú Kàn Bẹ̀rẹ̀ Abojuto Àwọn Bánkì Pẹ̀lú Ìlànà CBN Lórí Owó Tuntun
Ẹgbẹ́ àwùjọ aráàlú kàn, National Coalition On Improved Service Delivery (NACOISED) sọ pé òun tí ṣètò látí bẹ̀rẹ̀ abojuto àwọn bánkì ní ìbámu pẹ̀lú àṣẹ àtí ìlànà CBN látí ríi dájú pé àwọn ẹrọ ATM wọ́n ń pọ́ owó 200, 500 àtí 1000 tuntun…