NELFUND pín iye owó tó lé ní Bílíọ́nù mẹ́rìndínlọ́gọ́ta Náírà fún ẹ̀yáwó akẹ́kọ̀ọ́
Àjọ tí ń rísí owó yíyá fún ẹ̀kọ́ ní Nàìjíríà (NELFUND), ti kéde pínpín iye owó tó lé ní Bílíọ́nù mẹ́rìndínlọ́gọ́ta Náírà láìgba èlé fún àwọn ilé ẹ̀kọ́ gíga tíjọba jákèjádò orílẹ̀-èdè láti bí…