Igbákejì Ààrẹ Shettima Fẹ́ Ìlọsíwájú Ọrọ̀-Ajé Fún Àǹfààní Àwọn Aráàlú
Igbákejì Ààrẹ Kashim Shettima ti rọ àwọn Gómìnà ìpínlẹ̀ mẹ́rìndínlógójì ní Nàìjíríà, àwọn Mínísítà àti àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba mìíràn láti ṣiṣẹ́ láti ṣàṣeyọrí irú ìdàgbàsókè àti ìlọsíwájú ọrọ̀-ajé tó ń tàn kálẹ̀ sí ìgbésí ayé ojoojúmọ́ àwọn ọmọ…