ìdánilẹ́kọ̀ọ́ Ìkẹ́kọ̀ Bẹ̀rẹ̀ Fún Àwọn Olùkọ́ní Ní Ìpínlẹ̀ Ebonyi
Àjọ tó ń pèsè iṣẹ́ ní orílẹ̀-èdè yìí (National Directorate of Employment NDE) ní Ìpínlẹ̀ Ebonyi ní Gúúsù ìlà oòrùn Nàìjíríà tí bẹ̀rẹ̀ ikẹkọ àgbàrá fún àwọn olùkọ́ní rẹ̀.
ìdánilẹ́kọ̀ọ́ náà wáyé látí fí awọn òun èlò ìgbàlódé kọ́ àwọn…