Nàìjíríà ṣetán láti ṣe àpèjọ ààbò oúnjẹ alákọ̀ọ́kọ́ lórílẹ̀-èdè
Ìjọba Nàìjíríà ti ṣetán láti ṣagbatẹru alákọ̀ọ́kọ́ àpèjọ ètò Ọ̀gbìn lápapọ̀ àti ààbò oúnjẹ lórílẹ̀-èdè fún ìgbé ayé àlàáfíà àwọn àgbẹ̀, pèsè oúnjẹ lọ́pọ̀ àti láti yanjú àwọn ìpeniníjà tí ń…