Messi Fá Inter Miami Dé Èbúté Ògo Pẹ̀lú Bí Wọ́n Ṣé Gbá Ìfé Àkọ́kọ́
Lionel Messi gbá bọ́ọ̀lù àgbàyànú wọ́ awọ̀n bí ó ṣé gbá ìfé ẹ̀yẹ àkọ́kọ́ rẹ̀ ní Àríwá America bí Inter Miami ṣé ná Nashville ní àbálá ẹní bá láyà (10-9) lẹyìn tí Ifẹsẹwọnsẹ wọ́n ṣé parí ní ọ̀mì 1-1 ní iṣẹju àádọ́rún.
Messi ló kọ́kọ́…