Ìjọba Nàìjíríà Ṣé Ìdádúró Àwọn Àjọṣepọ̀ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Lókè Òkun Fún Ọdún Márún
Mínísítà fún ètò Ẹ̀kọ́, Dókítà Maruf Alausa, tí kéde ìdádúró ọdún márún lórí àjọṣepọ̀ ètò ẹ̀kọ́ lókè òkun látí ṣé ìdàgbàsókè àlàáfíà fún àwọn ọmọ Ilé-ìwé.
Nígbàtí o n sọrọ lẹ́yìn àtúnyẹwò nlá tí àwọn ètò ẹ̀kọ́ ní àwọn ìlú òkèèrè,…