Ikọ̀ Agbágbọ̀ọ̀lù Canada Gbìyànjú Láti Kán Ìyẹ́ Ikọ̀ Agbágbọ̀ọ̀lù Nàíjíríà Ṣùgbọ́n Super Falcon Ò…
Níbi ìdíje eré bọ́ọ̀lù àwọn obìnrin àgbáyé tó ń lọ lọ́wọ́, Ẹgbẹ́ Agbágbọ̀ọ̀lù Canada àti Super Falcon ti Ẹgbẹ́ Agbágbọ̀ọ̀lù Nàíjíríà jọ kojú ara wọn ní dédé aago mẹ́ta ààbọ̀ òwúrọ̀ (3:30am)
Ẹgbẹ́ Agbágbọ̀ọ̀lù Canada gbìyànjú…