Mínísítà fún ètò ìbáraẹnisọ̀rọ̀ pè fún ìdàgbàsókè orílẹ̀-èdè lẹ́yìn ìdájọ́…
Mínísítà Nàìjíríà fún ètò ìbáraẹnisọ̀rọ̀ àti ìfihàn lápapọ̀, Mohammed Idris ti rọ gbogbo ẹgbẹ́ olóṣèlú àti àwọn àgbààgbà ìlú láti mójú kúrò lórí ìdìbò, kí wọn ó sì gbájúmọ́ bí orílẹ̀-èdè yóò…