Kòsógun kòsíjà lórí Ààlà Kamẹrúùn àti Nàìjíríà
Ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti ṣàlàyé pé ìṣẹ̀lẹ̀ tó wáyé láìpẹ́ yìí kìí ṣe ogun bẹ́ẹ̀ni kìí sìí ṣe ìjà.
Oludari Agba fun igbimọ aala lorilẹ-ede lapapọ, Awọnlẹ Adamu Adaji,ṣalaye ni Abuja nibi apero kan lori…