Kòsí ìdánwò lọ́jọ́ ọdún o
Ìgbìmọ̀ tó ń ṣètò ìdánwò lórílẹ̀-èdè ,(NECO), sọ pé àwọn kò ṣètò ìdánwò èyíkéyìí fún ọjọ́ Àbáméta,ọjọ́ kẹsàn án, Oṣù Keje,ọdún 2022 nínú ìdánwò oníwèé ẹ̀rí Ilé-ìwé gíga tí ń lọ lọ́wọ́…