Kogi 2023: Ìfàsẹ́yìn bá LP bí àwọn alága ìjọba ìbílẹ̀ mọ́kànlé-lógún ṣe darapọ̀ mọ́…
Ẹgbẹ́ òṣèlú Labour, LP ti rí Ìfàsẹ́yìn bí gbogbo àwọn alága ìjọba ìbílẹ̀ mọ́kànlé-lógún rẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Kogi ṣe darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress, APC.
Awọn alaga naa darapọ mọ ẹgbẹ to n ṣejọba, APC…