NPFL: Pillars Gbó Ewúro Sójú Katsina United Ní Kano
Ìjà àjákü-akátá ní láàrín Kano Pillars àti Katsina United nínú ìdíje Agbabuta NPFL bí Pillars ṣé bóri pẹ̀lú àmì ayo kàn sí odò (1- 0) nínú ìfẹsẹ́wọ́nsẹ́ náà.
Pillars tó pàdánù ìfẹsẹ́wọ́nsẹ́ àkọ́kọ́ wọ́n ṣọwọ́ Sunshine ní Akure ló gbá…