Kamẹrúùn: Ààrùn onígbá méjì gbẹ̀mí ọ̀gọ́ọ́rọ́ ènìyàn
Ààrùn onígbá méjì ti tún padà sí orílè-èdè Kamẹrúùn,tí ó sì ti gbẹ̀mí ènìyàn tí ó ju mẹ́rìnlé-láàdọ́je lọ láti Oṣù Kẹwàá, ọdún 2021, níbi tí àwọn ènìyàn igba-lé-lẹ́gbàajọ ti ní ààrùn…