Iyọkuro Adinku: PDP rọ ìjọba láti jùmọ̀sọ̀rọ̀ pẹ̀lú ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́
Ẹgbẹ́ òṣèlú Peoples Democratic (PDP), ti rọ ìjọba Nàìjíríà láti jùmọ̀sọ̀rọ̀ pẹ̀lú ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ àti àwọn tó nííṣe láti yanjú ọ̀rọ̀ náà síbi tó rọrùn.
Ẹgbẹ́ náà pe ìpè yìí ní ọjọ́ Àbámẹ́ta, níbi àpèjọ…