Ìyànlóyè: Betara kí Gbajabiamila, Akume kú oríire
Ẹni tó ń dupò adarí ilé-ìgbìmọ̀ Aṣójú ẹlẹ́kẹwàá, Aṣojú Muktar Betara Aliyu, ti kí adarí ilé ìgbìmọ̀ Aṣojú, Aṣojú tó tifẹ̀yìntì, Fẹmi Gbajabiamila, gẹ́gẹ́ bí ọ̀gá àgbà fún àwọn òṣìṣẹ́ ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu,…