Quadri Gúnké Tábíìlì Ìwọ̀n ITTF, Mati Já Wálẹ̀
Gbájúgbájà agbágbọ̀ọ́lù ẹlẹ́yìn lóri tàbíìlì tó gá júlọ ní Áfíríkà, Aruna Quadri, sún sóke lóri tàbíìlì ìwọ̀n látí ìkéjidìnlógun sí ìkẹ́rindìnlógun lágbáyé fún àwọn ọkunrin.
Eyi wa lẹyin to ṣe aṣeyọri rẹ ninu idije "ITTF Africa Senior…