Israel – Ogunlọ́gọ̀ àwọn afẹ̀hónúhàn tú sí òpópónà
Ogunlọ́gọ̀ àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Isreal ti ṣe ìwọ́de tó lágbára jùlọ nínú ìtàn orílẹ̀-èdè náà.
Ìwọ́de lórí ìgbésẹ̀ ìjọba fún àtúnṣe tipátipá lórí ètò ìdájọ́ ti ń lọ lọ́wọ́ fún bíí ọ̀sẹ̀ mẹ́wàá…