Ipò orílẹ̀-èdè: Adarí ilé ìgbìmọ̀, Abbas pè fún sùúrù
Adarí ilé ìgbìmọ̀ aṣoju, Tajudeen Abbas, ti rọ àwọn ọmọ Nàìjíríà láti ní sùúrù bí ìjọba ṣe ń ṣiṣẹ́ lórí àtúnṣe ìgbé ayé wọn.
O pe ipe yii lasiko ipade awọn oniroyin lagbaye lori ipo orilẹ-ede,ní Abuja, olu ilu…