Ìpàdé Ààbò orílẹ̀-èdè Tẹ̀síwájú
Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí ń tẹ̀síwájú pẹ̀lú Ìpàdé Ààbò ní Víllà, Àbújá.
Ipade naa ti aarẹ orilẹ-ede Naijiria pe ni ọjọ Jimọh to kọja, ti sun siwaju titi di oni (Ọjọbọ).
O n waye ni yara Apejọ ti Iyaafin akọkọ,…