Ìmúkúrò Àdínkù : Ààrẹ Tinubu ń ṣiṣẹ́ lórí ìrọ̀rùn – APC Amẹ́ríkà
Alága fún ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress APC ní Amẹ́ríkà, Ọ̀jọ̀gbọ́n Tai Balofin ti rọ àwọn ọmọ Nàìjíríà láti gbàgbọ́ pé ààrẹ Bọla Tinubu, yóò ṣiṣẹ́ lórí ìrọ̀rùn tí yóò bomi sí títa ríro àyọkúrò owó…