Ilé ìgbìmọ̀ Gombe ẹlẹ́ẹ̀keje tún Lugerewo yàn bí adarí
Wọ́n tún ti tún Alhaji Mohammed Lugerewo, tí ó jẹ́ adarí ilé ìgbìmọ̀ ẹlẹ́ẹ̀kẹfà tó ṣẹ̀ṣẹ̀ parí yìí ní ipinlẹ Gombe, gẹ́gẹ́ bí adarí ilé ìgbìmọ̀ ẹlẹ́ẹ̀keje ní iịpínlẹ̀ náà.
Lugerewo, tí ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ All…