Ilé ìgbìmọ̀ Aṣojú Ṣèwádìí bí epo ilẹ̀ àti Gáásì fi gbówólérí
Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣojú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ti kàn án nípá fún ìgbìmọ̀ rẹ̀ lórí Àwọn orísun Epo ilẹ̀ àti ọ̀rọ̀ Gáásì láti ṣe ìwádìí ìgbówólórí epo ilẹ̀ àti gáásì ìdáná ní orílẹ̀-èdè láìpẹ́…