Ilé Aṣòfin bẹnu àtẹ́ lu fífi àwọn ọ̀dọ́ bìnrin rúbọ
Ilé ìgbìmọ̀ Aṣojú ṣòfin ti fi ẹ̀dùn ọkàn wọn hàn lórí bí wọ́n ṣe ń pa àwọn ọ̀dọ́ bìnrin láti fi rúbọ.
Ile igbimọ naa tun banujẹ lori pe awọn ọdọ kunrin ni o n hu iwa aburu yii, ti o si jẹ wipe wọn le maa le da iṣe naa ṣe…