Ìjọba Nàìjíríà ti Ṣetán Láti Dín Owó ìṣàkóso ìjọba kù
Ìjọba Nàìjíríà ti sọ pé òhun yóò ṣe àtúnyẹ̀wò owó àwọn òṣìṣẹ́ àti àwọn ilé iṣẹ́ rẹ̀ nípasẹ̀ àti dín owó ìsàkóso ìjọba kù .
Minisita fun eto inawo, eto isuna ati eto ilu, Iyaafin Zainab Ahmed kede eleyi nibi…